信的人必能施行異跡、就是靠我的名趕鬼、說外邦的方言、 手能拿蛇、若喝了毒物、也不受害、按手在病人身上、病人就得痊愈了、○
Kà 馬可福音 16
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: 馬可福音 16:17-18
3 Awọn ọjọ
Ìbí, ikú àti àjíǹde Jésù mú ìròyìn ayọ̀ náà wá. Ìròyìn ayọ̀ yìí ni ó ti yọrí sí ìgbàlà arayé. Nítorí náà, gbogbo ẹni tí a ti gbàlà ni Jésù Olúwa àti Olùgbàlà ti pa á láṣẹ fún láti dìde fún ìgbàlà àwọn ẹlòmíràn nípasẹ̀ ìkéde-ìhìnrere, èyí tíí ṣe pínpín ìròyìn ayọ̀ yìí kan náà fún àwọn ẹlòmíràn tí kò tíì di ẹni ìgbàlà.
5 Days
God is awakening His Church, and we need to see the big picture. When times get tough, we will be tempted to quit. It is not, however, time to quit. Join us as we learn how to read the times we are in, as well as gain strategies on how to stand and advance the Kingdom of God.
7 days
There is a dynamic, dead-raising power on the inside of you. Evangelist Reinhard Bonnke has penned some strong teachings on the Holy Spirit for you and has written dynamic Points of Power on the Holy Spirit. This 7 Day Study will challenge your thinking on the Holy Spirit and inspire you to believe in the amazing power of the Spirit within you.
7 Awọn ọjọ
Kété lẹ́yìn tí Jésù jíǹde kúrò nínú ikú, ó wà lórí ilẹ̀ ayé fún ogójì [40] ọjọ́ sí i, ó sì pàṣẹ fáwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ pé kí wọ́n lọ sí gbogbo ayé kí wọ́n sì wàásù ìhìn rere, lẹ́yìn náà ó tẹ̀ lé àwọn àmì tó yẹ kó máa tẹ̀ lé onígbàgbọ́. . Ni ọsẹ yii, a fẹ lati wo awọn ami wọnyi ni pẹkipẹki. O jẹ adura mi pe Ẹmi Mimọ yoo ṣii oju wa si ifihan nla lori koko-ọrọ naa.
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò