ORIN DAFIDI 8:5-7

ORIN DAFIDI 8:5-7 YCE

O dá a, ipò rẹ̀ rẹlẹ̀ díẹ̀ sí ti ìwọ Ọlọrun, o sì ti fi ògo ati ọlá dé e ní adé. O mú un jọba lórí àwọn iṣẹ́ ọwọ́ rẹ, o sì fi gbogbo nǹkan sí abẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀: àwọn aguntan, ati àwọn mààlúù, ati gbogbo ẹranko ninu igbó