ORIN DAFIDI 60:12

ORIN DAFIDI 60:12 YCE

Pẹlu àtìlẹ́yìn Ọlọrun a óo ṣe akin, nítorí òun ni yóo tẹ àwọn ọ̀tá wa mọ́lẹ̀.