ORIN DAFIDI 59:9-10
ORIN DAFIDI 59:9-10 YCE
Ọlọrun, agbára mi, ojú rẹ ni mò ń wò, nítorí ìwọ, Ọlọrun, ni odi mi. Ọlọrun mi óo wá sọ́dọ̀ mi ninu ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀; Ọlọrun óo fún mi ní ìṣẹ́gun lórí àwọn ọ̀tá mi.