ORIN DAFIDI 132:4-5

ORIN DAFIDI 132:4-5 YCE

n kò ní sùn, bẹ́ẹ̀ ni n kò ní tòògbé, títí tí n óo fi wá ààyè fún OLUWA, àní, tí n óo fi pèsè ibùgbé fún ìwọ Alágbára, Ọlọrun Jakọbu.”