ORIN DAFIDI 128:1

ORIN DAFIDI 128:1 YCE

Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí ó bẹ̀rù OLÚWA, tí ó sì ń tẹ̀lé ìlànà rẹ̀.