ORIN DAFIDI 102:13

ORIN DAFIDI 102:13 YCE

Ìwọ óo dìde, o óo sì ṣàánú Sioni, nítorí ó tó àkókò láti fi ojú àánú wò ó. Àkókò tí o dá tó.