ÌWÉ ÒWE 3:27

ÌWÉ ÒWE 3:27 YCE

Má ṣe fa ọwọ́ ire sẹ́yìn lọ́dọ̀ àwọn tí ó tọ́ sí, nígbà tí ó bá wà ní ìkáwọ́ rẹ láti ṣe é.