ÌWÉ ÒWE 15:18-19

ÌWÉ ÒWE 15:18-19 YCE

Onínúfùfù a máa rú ìjà sókè, ṣugbọn onínútútù a máa pẹ̀tù sí ibinu. Ẹ̀gún kún bo ọ̀nà ọ̀lẹ, ṣugbọn ọ̀nà olódodo dàbí òpópó tí ń dán.