ÌWÉ ÒWE 13:10

ÌWÉ ÒWE 13:10 YCE

Ìjà ni ìgbéraga máa ń fà, ṣugbọn àwọn tí wọ́n bá gba ìmọ̀ràn yóo ní ọgbọ́n.