MATIU 9:4

MATIU 9:4 YCE

Ṣugbọn Jesu mọ èrò inú wọn; ó bá bi wọ́n pé, “Kí ló dé tí ẹ fi ń ro èrò burúkú ninu ọkàn yín?

Àwọn fídíò fún MATIU 9:4