MATIU 24:5

MATIU 24:5 YCE

Nítorí ọ̀pọ̀ ni yóo wá ní orúkọ mi, tí wọn yóo máa sọ pé, ‘Èmi gan-an ni Mesaya náà,’ wọn yóo sì tan ọpọlọpọ jẹ.

Àwọn fídíò fún MATIU 24:5