Ẹ dìde, ẹ kígbe lálẹ́, ní àkókò tí àwọn aṣọ́de ń bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́! Ẹ tú ẹ̀dùn ọkàn yín jáde bí omi níwájú OLUWA! Ẹ gbé ọwọ́ ẹ̀bẹ̀ sókè sí i, nítorí ẹ̀mí àwọn ọmọ yín tí ebi ń pa kú lọ ní gbogbo ìkóríta.
Kà ẸKÚN JEREMAYA 2
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ẸKÚN JEREMAYA 2:19
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò