ÀWỌN ADÁJỌ́ 13:1

ÀWỌN ADÁJỌ́ 13:1 YCE

Àwọn ọmọ Israẹli tún ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA, OLUWA sì fi wọ́n lé àwọn ará Filistia lọ́wọ́. Wọ́n sin àwọn ará Filistia fún ogoji ọdún.