AISAYA 43:1

AISAYA 43:1 YCE

Ṣugbọn nisinsinyii, Jakọbu, gbọ́ nǹkan tí OLUWA ẹlẹ́dàá rẹ wí, Israẹli, gbọ́ ohun tí ẹni tí ó dá ọ sọ. Ó ní, “Má bẹ̀rù, nítorí mo ti rà ọ́ pada; mo ti pè ọ́ ní orúkọ rẹ, èmi ni mo ni ọ́.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún AISAYA 43:1

AISAYA 43:1 - Ṣugbọn nisinsinyii, Jakọbu,
gbọ́ nǹkan tí OLUWA ẹlẹ́dàá rẹ wí,
Israẹli, gbọ́ ohun tí ẹni tí ó dá ọ sọ.
Ó ní, “Má bẹ̀rù, nítorí mo ti rà ọ́ pada;
mo ti pè ọ́ ní orúkọ rẹ, èmi ni mo ni ọ́.