HOSIA 11:3-4

HOSIA 11:3-4 YCE

Bẹ́ẹ̀ ni èmi ni mo kọ́ Efuraimu ní ìrìn, mo gbé wọn lé ọwọ́ mi, ṣugbọn wọn kò mọ̀ pé èmi ni mo wo àwọn sàn. Mo fà wọ́n mọ́ra pẹlu okùn àánú ati ìdè ìfẹ́, mo dàbí ẹni tí ó tú àjàgà kúrò ní ẹ̀rẹ̀kẹ́ wọn, mo sì bẹ̀rẹ̀, mo gbé oúnjẹ kalẹ̀ níwájú wọn.