OLUWA ní, “Nígbà tí Israẹli wà ní ọmọde, mo fẹ́ràn rẹ̀, láti ilẹ̀ Ijipti ni mo sì ti pe ọmọ mi jáde. Ṣugbọn bí mo ti ń pè wọ́n tó, bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n ń sá fún mi, wọ́n ń rúbọ sí àwọn oriṣa Baali, wọ́n ń sun turari sí ère.
Kà HOSIA 11
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: HOSIA 11:1-2
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò