OLUWA bá bi mí léèrè, ó ní, “Ìwọ ọmọ eniyan, ǹjẹ́ àwọn egungun wọnyi lè tún jí?” Mo bá dáhùn, mo ní, “OLUWA, ìwọ nìkan ni o mọ̀.” Ó bá sọ fún mi pé, “Sọ àsọtẹ́lẹ̀ fún àwọn egungun wọnyi, kí o wí fún wọn pé, ‘Ẹ̀yin egungun gbígbẹ wọnyi, ẹ gbọ́ ohun tí OLUWA wí’. Ó ní: ‘N óo mú kí èémí wọ inú yín, ẹ óo sì di alààyè.
Kà ISIKIẸLI 37
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ISIKIẸLI 37:3-5
4 Ọjọ
Awọn Ere Awọn Nkan Nla Meji ti soju iṣẹlẹ ti ọkanlẹlo diẹ ninu Bibeli, ti o soju awọn ohun orisun ara Jesu ti a gbọdọ ni a gbẹ nipa lati wa ni Kristiani ti o le ṣe iṣẹlẹ ti o dara. Nitorina pe a le soju iṣẹlẹ ọlọgbo lati mọ bii o le kede awọn iṣeduro ti o yẹ lati gba lati gba iṣẹlẹ ni ẹjẹ rere rẹ."
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò