ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 1:8

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 1:8 YCE

Gbogbo nǹkan ní ń kó àárẹ̀ bá eniyan, ju bí ẹnu ti lè sọ lọ. Ìran kì í sú ojú, bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ kì í kún etí.