ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 5:42

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 5:42 YCE

Lojoojumọ, ninu Tẹmpili ati láti ilé dé ilé, wọn kò dẹ́kun láti máa kọ́ eniyan ati láti máa waasu pé Jesu ni Mesaya.