ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 1:14

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 1:14 YCE

Gbogbo wọn ń fi ọkàn kan gbadura nígbà gbogbo pẹlu àwọn obinrin ati Maria ìyá Jesu ati àwọn arakunrin Jesu.