SAMUẸLI KEJI 1:26

SAMUẸLI KEJI 1:26 YCE

“Mò ń ṣe ìdárò rẹ, Jonatani arakunrin mi; o ṣọ̀wọ́n fún mi lọpọlọpọ. Ìfẹ́ tí o ní sí mi, kò ṣe é fi ẹnu sọ, ó ju ìfẹ́ obinrin lọ.