KRONIKA KEJI 1:7

KRONIKA KEJI 1:7 YCE

Ní òru ọjọ́ náà, Ọlọrun fara han Solomoni, ó wí fún un pé “Bèèrè ohun tí o bá fẹ́ kí n fún ọ.”