ÀWỌN ỌBA KINNI 3:5

ÀWỌN ỌBA KINNI 3:5 YCE

OLUWA fara han Solomoni ní ojú àlá ní òru ọjọ́ kan ní Gibeoni, ó sì bi í pé, “Kí ni o fẹ́ kí n fún ọ?”