KỌRINTI KINNI 3:13

KỌRINTI KINNI 3:13 YCE

iṣẹ́ olukuluku yóo farahàn kedere ní ọjọ́ ìdájọ́, nítorí iná ni yóo fi í hàn. Iná ni a óo fi dán iṣẹ́ olukuluku wò.