1
Sekariah 1:3
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Nítorí náà sọ fún àwọn ènìyàn. Èyí ni ohun tí OLúWA àwọn ọmọ-ogun wí: ‘Ẹ padà sí ọ̀dọ̀ mi,’ báyìí ní OLúWA àwọn ọmọ-ogun wí, ‘èmi náà yóò sì padà sí ọ̀dọ̀ yín,’ ni OLúWA àwọn ọmọ-ogun wí.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Sekariah 1:3
2
Sekariah 1:17
“Máa ké síbẹ̀ pé, báyìí ni OLúWA àwọn ọmọ-ogun wí, ‘A o máa fi ìre kún ìlú ńlá mi síbẹ̀; OLúWA yóò sì máa tu Sioni nínú síbẹ̀, yóò sì yan Jerusalẹmu síbẹ̀.’ ”
Ṣàwárí Sekariah 1:17
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò