1
Orin Solomoni 5:16
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Ẹnu rẹ̀ jẹ́ adùn fún ara rẹ̀ ó wu ni pátápátá. Háà! Ẹ̀yin ọmọbìnrin Jerusalẹmu. Èyí ni olùfẹ́ mi, èyí sì ni ọ̀rẹ́ mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Orin Solomoni 5:16
2
Orin Solomoni 5:10
Olùfẹ́ mi ní ìtànṣán ó sì pọ́n ó ní ọlá ju ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) lọ.
Ṣàwárí Orin Solomoni 5:10
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò