1
Saamu 98:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Ẹ kọrin tuntun sí OLúWA, nítorí tí ó ṣe ohun ìyanu; ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ àti apá mímọ́ rẹ̀ o ṣe iṣẹ́ ìgbàlà fún un
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 98:1
2
Saamu 98:4
Ẹ hó ìhó ayọ̀ sí OLúWA, gbogbo ayé, ẹ bú sáyọ̀, ẹ kọrin ìyìn
Ṣàwárí Saamu 98:4
3
Saamu 98:9
ẹ jẹ́ kí wọn kọrin níwájú OLúWA, nítorí tí yóò wá ṣèdájọ́ ayé bẹ́ẹ̀ ni yóò ṣe ìdájọ́ àwọn orílẹ̀-èdè nínú òdodo àti àwọn ènìyàn ní àìṣègbè pẹ̀lú.
Ṣàwárí Saamu 98:9