Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Saamu 68

1

Saamu 68:19

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Olùbùkún ni OLúWA, Ọlọ́run Olùgbàlà wa, ẹni tí ó ń fi ojoojúmọ́ gba ẹrù wa rù. Sela.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 68:19

2

Saamu 68:5

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Baba àwọn aláìní baba àti onídàájọ́ àwọn opó ni Ọlọ́run ní ibùgbé rẹ̀ mímọ́

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 68:5

3

Saamu 68:6

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ọlọ́run gbé aláìlera kalẹ̀ nínú ìdílé, ó darí àwọn ẹlẹ́wọ̀n pẹ̀lú orin, ṣùgbọ́n àwọn ọlọ́tẹ̀ ní ń gbé nínú ilẹ̀ gbígbẹ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 68:6

4

Saamu 68:20

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ọlọ́run wa jẹ́ Ọlọ́run tó ń gbàlà àti sí OLúWA Olódùmarè ni ó ń gbà wá lọ́wọ́ ikú.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 68:20

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Saamu 68

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò