Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Saamu 41

1

Saamu 41:1

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ìbùkún ni fún ẹni tí ó ń ro ti aláìní: OLúWA yóò gbà á ní ìgbà ìpọ́njú.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 41:1

2

Saamu 41:3

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

OLúWA yóò gbà á lórí àkéte àìsàn rẹ̀ yóò sì mú un padà bọ̀ sípò kúrò nínú àìsàn rẹ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 41:3

3

Saamu 41:12

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Bí ó ṣe tèmi ni ìwọ dì mímú nínú ìwà òtítọ́ mi ìwọ sì gbé mi kalẹ̀ níwájú rẹ títí láé.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 41:12

4

Saamu 41:4

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ní ti èmi, mo wí pé “OLúWA, ṣàánú fún mi; wò mí sàn, nítorí pé mo ti ṣẹ̀ sí ọ”.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 41:4

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
Yorùbá

©2026 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest