Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Saamu 30

1

Saamu 30:5

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Nítorí pé ìbínú rẹ̀ wà fún ìgbà díẹ̀, ojúrere rẹ̀ wà títí ayérayé; ẹkún lè pẹ́ títí di alẹ́, ṣùgbọ́n ayọ̀ yóò wá ní òwúrọ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 30:5

2

Saamu 30:11-12

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ìwọ ti yí ìkáàánú mi di ijó fún mi; ìwọ sì ti bọ́ aṣọ ọ̀fọ̀ mi, o sì fi aṣọ ayọ̀ wọ̀ mí, nítorí ìdí èyí ni kí ọkàn mi máa yìn ọ́, kí o má sì ṣe dákẹ́. Ìwọ OLúWA Ọlọ́run mi, èmi yóò máa fi ọpẹ́ fún ọ títí láé.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 30:11-12

3

Saamu 30:2

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

OLúWA Ọlọ́run mi, èmi ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́, ìwọ sì ti wò mí sàn.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 30:2

4

Saamu 30:4

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Kọ orin ìyìn sí OLúWA, ẹ̀yin olódodo; kí ẹ sì fi ọpẹ́ fún orúkọ rẹ̀ mímọ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 30:4

5

Saamu 30:1

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Èmi yóò kókìkí i rẹ, OLúWA, nítorí ìwọ ni ó gbé mi lékè tí ìwọ kò sì jẹ́ kí àwọn ọ̀tá mi kí ó yọ̀ mí.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 30:1

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Saamu 30

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
Yorùbá

©2026 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest