1
Saamu 23:4
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Bí mo tilẹ̀ ń rìn láàrín àfonífojì òjìji ikú, èmi kì yóò bẹ̀rù ibi kan, nítorí ìwọ wà pẹ̀lú mi; ọ̀gọ rẹ àti ọ̀pá à rẹ, wọ́n ń tù mí nínú.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 23:4
2
Saamu 23:1
OLúWA ni olùṣọ́ èmi àgùntàn rẹ̀, èmi kì yóò ṣe aláìní.
Ṣàwárí Saamu 23:1
3
Saamu 23:6
Nítòótọ́, ìre àti àánú ni yóò máa tọ̀ mí lẹ́yìn ní ọjọ́ ayé è mi gbogbo, èmi yóò sì máa gbé inú ilé OLúWA títí láéláé.
Ṣàwárí Saamu 23:6
4
Saamu 23:2-3
Ó mú mi dùbúlẹ̀ sí ibi pápá oko tútù, Ó mú mi lọ sí ibi omi dídákẹ́ rọ́rọ́, Ó mú ọkàn mi padà bọ̀ sípò. Ó mú mi lọ sí ọ̀nà òdodo nítorí orúkọ rẹ̀.
Ṣàwárí Saamu 23:2-3
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò