Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Saamu 16

1

Saamu 16:11

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ìwọ ti fi ipa ọ̀nà ìyè hàn mí; Ìwọ yóò kún mi pẹ̀lú ayọ̀ ní iwájú rẹ, pẹ̀lú ìdùnnú ayérayé ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 16:11

2

Saamu 16:8

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Mo ti gbé OLúWA síwájú mi ní ìgbà gbogbo. Nítorí tí ó wà ní ọwọ́ ọ̀tún mi, a kì yóò mì mí.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 16:8

3

Saamu 16:5

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

OLúWA, ni ìpín ìní mi tí mo yàn àti ago mi, ó ti pa ohun tí í ṣe tèmi mọ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 16:5

4

Saamu 16:7

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Èmi yóò yin OLúWA, ẹni tí ó gbà mí ní ìyànjú; ní òru, ọkàn mí ń bá mi sọ̀rọ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 16:7

5

Saamu 16:6

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Okùn ààlà ilẹ̀ ti bọ́ sí ọ̀dọ̀ mi ní ibi dídára; nítòótọ́ mo ti ní ogún rere.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 16:6

6

Saamu 16:1

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Pa mí mọ́, Ọlọ́run, nítorí nínú rẹ ni ààbò mi wà.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 16:1

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Saamu 16

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
Yorùbá

©2026 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest