1
Saamu 127:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Bí kò ṣe pé OLúWA bá kọ́ ilé náà àwọn tí ń kọ́ ọ ń ṣiṣẹ́ lásán ni; bí kò ṣe pé OLúWA bá pa ìlú mọ́, olùṣọ́ jí lásán.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 127:1
2
Saamu 127:3-4
Kíyèsi i, àwọn ọmọ ni ìní OLúWA: ọmọ inú sì ni èrè rẹ̀. Bí ọfà ti rí ní ọwọ́ alágbára, bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ èwe.
Ṣàwárí Saamu 127:3-4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò