Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Saamu 11

1

Saamu 11:7

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Nítorí, olódodo ní OLúWA, o fẹ́ràn òdodo; ẹni ìdúró ṣinṣin yóò sì rí i.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 11:7

2

Saamu 11:4

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

OLúWA ń bẹ nínú tẹmpili mímọ́ rẹ̀; OLúWA ń bẹ lórí ìtẹ́ rẹ̀ ní ọ̀run. Ó ń wo àwọn ọmọ ènìyàn; ojú rẹ̀ ń yẹ̀ wọ́n wò.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 11:4

3

Saamu 11:5

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

OLúWA ń yẹ olódodo wò, ṣùgbọ́n ènìyàn búburú àti àwọn tí o fẹ́ ìwà ipá ni ọkàn rẹ̀ kórìíra.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 11:5

4

Saamu 11:3

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Nígbà tí ìpìlẹ̀ bá bàjẹ́ kí ni olódodo yóò ṣe?”

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 11:3

5

Saamu 11:1

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ìgbẹ́kẹ̀lé mi wà nínú OLúWA. Báwo ní ẹ̀yin ó ṣe sọ fún ọkàn mi pé, “Fò gẹ́gẹ́ bi ẹyẹ lọ si orí òkè rẹ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 11:1

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Saamu 11

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
Yorùbá

©2026 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest