1
Obadiah 1:17
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Ṣùgbọ́n ìgbàlà yóò wà lórí òkè Sioni, wọn yóò sì jẹ́ mímọ́, àti ilé Jakọbu yóò sì ní ìní wọn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Obadiah 1:17
2
Obadiah 1:15
“Nítorí ọjọ́ OLúWA súnmọ́ etílé lórí gbogbo àwọn kèfèrí. Bí ìwọ ti ṣe, bẹ́ẹ̀ ni a ó ṣe sí ìwọ náà; ẹ̀san rẹ yóò sì yípadà sí orí ara rẹ.
Ṣàwárí Obadiah 1:15
3
Obadiah 1:3
Ìgbéraga àyà rẹ ti tàn ọ́ jẹ, ìwọ tí ń gbé inú pálapàla àpáta, tí o sì kọ́ ibùgbé rẹ sí ibi gíga, ìwọ wí nínú ọkàn rẹ pé, ‘Ta ni yóò mú mi sọ̀kalẹ̀?’
Ṣàwárí Obadiah 1:3
4
Obadiah 1:4
Bí ìwọ tilẹ̀ gbé ara rẹ ga bí ẹyẹ idì, bí ìwọ tilẹ̀ tẹ́ ìtẹ́ rẹ sí àárín àwọn ìràwọ̀, láti ibẹ̀ ni èmi yóò ti sọ̀ ọ kalẹ̀,” ni OLúWA wí.
Ṣàwárí Obadiah 1:4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò