Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Lefitiku 10

1

Lefitiku 10:1

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Nadabu àti Abihu tí í ṣe ọmọ Aaroni sì mú àwo tùràrí kọ̀ọ̀kan, wọ́n fi iná àti tùràrí sínú rẹ̀, wọ́n sì rú iná àjèjì níwájú OLúWA, èyí tó lòdì sí àṣẹ OLúWA.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Lefitiku 10:1

2

Lefitiku 10:3

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Mose sì sọ fún Aaroni pé, “Ohun tí OLúWA ń sọ nípa rẹ̀ nìyìí nígbà tó wí pé, “ ‘Ní àárín àwọn tó súnmọ́ mi, Èmi yóò fi ara mi hàn ní mímọ́ ojú gbogbo ènìyàn Ní a ó ti bu ọlá fún mi.’ ” Aaroni sì dákẹ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Lefitiku 10:3

3

Lefitiku 10:2

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Torí èyí, iná jáde láti ọ̀dọ̀ OLúWA, ó sì jó wọn pa, wọ́n sì kú níwájú OLúWA.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Lefitiku 10:2

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Lefitiku 10

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò