1
Ẹkun Jeremiah 2:19
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
YCB
Dìde, kígbe sókè ní àṣálẹ́, bí ìṣọ́ òru ti bẹ̀rẹ̀ tú ọkàn rẹ̀ jáde bí omi níwájú OLúWA. Gbé ọwọ́ yín sókè sí i nítorí ẹ̀mí àwọn èwe rẹ̀ tí ó ń kú lọ nítorí ebi ní gbogbo oríta òpópó.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Ẹkun Jeremiah 2:19
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò