Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Joṣua 24

1

Joṣua 24:15

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

YCB

Ṣùgbọ́n bí ẹ̀yin kò bá fẹ́ láti sin OLúWA, nígbà náà ẹ yàn fún ara yín ní òní ẹni tí ẹ̀yin yóò sìn bóyá òrìṣà tí àwọn baba ńlá yín sìn ní ìkọjá odò Eufurate, tàbí òrìṣà àwọn ará Amori, ní ilẹ̀ ẹni tí ẹ̀yin ń gbé. Ṣùgbọ́n ní ti èmi àti ilé mi, OLúWA ni àwa yóò máa sìn.”

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Joṣua 24:15

2

Joṣua 24:14

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

YCB

“Nísinsin yìí ẹ bẹ̀rù OLúWA, kí ẹ sì máa sìn ín ní òtítọ́ àti òdodo. Kí ẹ sì mú òrìṣà tí àwọn baba ńlá yín sìn ní ìkọjá odò Eufurate àti ní Ejibiti kúrò, kí ẹ sì máa sin OLúWA.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Joṣua 24:14

3

Joṣua 24:16

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

YCB

Àwọn ènìyàn sì dáhùn pé, “Kí a má ri tí àwa yóò fi kọ OLúWA sílẹ̀ láti sin òrìṣà!

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Joṣua 24:16

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò