1
Joṣua 22:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
YCB
Ṣùgbọ́n ẹ ṣọ́ra gidigidi láti pa àṣẹ àti òfin tí Mose ìránṣẹ́ OLúWA fi fún yin mọ́. Láti fẹ́ràn OLúWA Ọlọ́run yín, láti rìn nínú gbogbo ọ̀nà rẹ̀, láti gbọ́rọ̀ sí àṣẹ rẹ̀, láti dìímú ṣinṣin àti láti sìn ín pẹ̀lú gbogbo ọkàn yín àti gbogbo àyà yín.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Joṣua 22:5
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò