1
Jeremiah 26:13
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Nísinsin yìí, tún ọ̀nà rẹ ṣe àti ìṣe rẹ, kí ẹ sì gbọ́ ọ̀rọ̀ OLúWA Ọlọ́run yín. OLúWA yóò yí ọkàn rẹ̀ padà, kò sì ní mú ohun gbogbo tí ó ti sọ jáde ní búburú ṣẹ lórí yín.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Jeremiah 26:13
2
Jeremiah 26:3
Bóyá gbogbo wọn máa gbọ́ ọ̀rọ̀ náà tí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn yóò kúrò nínú ìwà búburú wọn. Èmi ó yí ọkàn padà, n kò sì ní fi ibi tí mo ti rò sí wọn ṣe wọ́n.
Ṣàwárí Jeremiah 26:3
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò