1
Jeremiah 16:21
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
“Nítorí náà, Èmi yóò kọ́ wọn ní àkókò yìí, Èmi yóò kọ́ wọn pẹ̀lú agbára àti títóbi mi. Nígbà náà ni wọn ó mọ pé orúkọ mi ní OLúWA.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Jeremiah 16:21
2
Jeremiah 16:19
OLúWA, alágbára àti okun mi, ẹni ààbò mi ní ọjọ́ ìpọ́njú, àwọn orílẹ̀-èdè yóò wá láti òpin ayé wí pé, “Àwọn baba ńlá wa kò ní ohun kan bí kò ṣe ẹ̀gbin òrìṣà, ìríra tí kò dára fún wọn nínú rẹ̀.
Ṣàwárí Jeremiah 16:19
3
Jeremiah 16:20
Ṣé àwọn ènìyàn lè dá Ọlọ́run fún ara wọn bí? Bẹ́ẹ̀ ni, ṣùgbọ́n àwọn wọ̀nyí kì í ṣe Ọlọ́run.”
Ṣàwárí Jeremiah 16:20
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò