1
Esekiẹli 14:6
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
YCB
“Nítorí náà sọ fún ilé Israẹli, ‘Èyí ni ohun tí OLúWA Olódùmarè wí: Ẹ ronúpìwàdà! Ẹ yípadà kúrò lọ́dọ̀ òrìṣà yín, kí ẹ̀yin sì kọ gbogbo ìwà ìríra yín sílẹ̀!
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Esekiẹli 14:6
2
Esekiẹli 14:5
Èmi yóò ṣe èyí láti gba ọkàn àwọn ará Israẹli tó ti tẹ̀lé òrìṣà wọn lọ padà sí ọ̀dọ̀ mi.’
Ṣàwárí Esekiẹli 14:5
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò