1
Oniwaasu 6:9
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
YCB
Ohun tí ojú rí sàn ju ìfẹnuwákiri lọ Asán ni eléyìí pẹ̀lú ó dàbí ẹni ń gbìyànjú àti mú afẹ́fẹ́.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Oniwaasu 6:9
2
Oniwaasu 6:10
Ohunkóhun tí ó bá ti wà ti ní orúkọ, ohun tí ènìyàn jẹ́ sì ti di mí mọ̀; kò sí ènìyàn tí ó le è ja ìjàkadì pẹ̀lú ẹni tí ó lágbára jù ú lọ
Ṣàwárí Oniwaasu 6:10
3
Oniwaasu 6:2
Ọlọ́run fún ọkùnrin kan ní ọrọ̀, ọlá àti ọlà kí ó má ba à ṣe aláìní ohunkóhun tí ọkàn rẹ̀ ń fẹ́. Ṣùgbọ́n, Ọlọ́run kò fún un ní àǹfààní láti gbádùn wọn, dípò èyí, àlejò ni ó ń gbádùn wọn. Asán ni èyí, ààrùn búburú gbá à ni.
Ṣàwárí Oniwaasu 6:2
4
Oniwaasu 6:7
Gbogbo wàhálà tí ènìyàn ń ṣe nítorí àtijẹ ni síbẹ̀ ikùn rẹ̀ kò yó rí
Ṣàwárí Oniwaasu 6:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò