1
Ìṣe àwọn Aposteli 24:16
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Nínú èyí ni èmi sì ti ń gbìyànjú láti ní ẹ̀rí ọkàn tí kò lẹ́sẹ̀ sí Ọlọ́run, àti sí ènìyàn nígbà gbogbo.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 24:16
2
Ìṣe àwọn Aposteli 24:25
Bí Paulu sì tí ń sọ àsọyé nípa tí òdodo àti àìrékọjá àti ìdájọ́ tí ń bọ̀, ẹ̀rù ba Feliksi, ó dáhùn wí pé, “Èyí tí o sọ nì tó ná! Máa lọ nísinsin yìí ná. Nígbà tí mo bá sì ní àkókò tí ó wọ̀, èmi ó ránṣẹ́ pè ọ́.”
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 24:25
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò