1
1 Tẹsalonika 4:17
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Nígbà náà ni a ó gba àwa tí ó sì wà láààyè sókè nínú àwọsánmọ̀ láti ọwọ́ Olúwa. A ó sì wà pẹ̀lú rẹ̀ títí láéláé.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí 1 Tẹsalonika 4:17
2
1 Tẹsalonika 4:16
Nítorí pé, Olúwa fúnra rẹ̀ yóò sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀run wá, pẹ̀lú ariwo àṣẹ ńlá àti ohùn àwọn angẹli ti àwọn angẹli ti àwọn ti ìpè Ọlọ́run, àwọn òkú nínú Kristi yóò sì kọ́kọ́ jíǹde.
Ṣàwárí 1 Tẹsalonika 4:16
3
1 Tẹsalonika 4:3-4
Nítorí ìfẹ́ Ọlọ́run ni pé kí ẹ jẹ́ mímọ́, kí ẹ sì yàgò kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ àgbèrè, kí ẹnìkọ̀ọ̀kan yín kọ́ láti ṣàkóso ara rẹ̀ ní ọ̀nà mímọ́ àti pẹ̀lú ọlá
Ṣàwárí 1 Tẹsalonika 4:3-4
4
1 Tẹsalonika 4:14
A gbàgbọ́ pé, Jesu kú, ó sì tún jíǹde, àti pé Ọlọ́run yóò mú gbogbo àwọn tí ó ti sùn nínú rẹ̀ padà wá.
Ṣàwárí 1 Tẹsalonika 4:14
5
1 Tẹsalonika 4:11
Ẹ jẹ́ kí èyí jẹ́ ìfẹ́ ọkàn yín láti gbé jẹ́ẹ́ àti láti mọ ti ara yín àti kí olúkúlùkù kọjú sí iṣẹ́ rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí a ti wí fún yín.
Ṣàwárí 1 Tẹsalonika 4:11
6
1 Tẹsalonika 4:7
Nítorí Ọlọ́run kò pè wá sínú ìwà èérí, bí kò ṣe sínú ìgbé ayé mímọ́.
Ṣàwárí 1 Tẹsalonika 4:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò