Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ 1 Samuẹli 15

1

1 Samuẹli 15:22

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ṣùgbọ́n Samuẹli dáhùn pé, “OLúWA ha ní inú dídùn sí ẹbọ sísun àti ẹbọ ju kí a gba ohùn OLúWA gbọ́? Ìgbọ́ràn sàn ju ẹbọ lọ, ìfetísílẹ̀ sì sàn ju ọ̀rá àgbò lọ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí 1 Samuẹli 15:22

2

1 Samuẹli 15:23

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Nítorí pé ìṣọ̀tẹ̀ dàbí ẹ̀ṣẹ̀ àfọ̀ṣẹ, àti ìgbéraga bí ẹ̀ṣẹ̀ ìbọ̀rìṣà. Nítorí tí ìwọ ti kọ ọ̀rọ̀ OLúWA, Òun sì ti kọ̀ ọ́ ní ọba.”

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí 1 Samuẹli 15:23

3

1 Samuẹli 15:29

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ẹni tí ó ń ṣe ògo Israẹli, kì í purọ́, bẹ́ẹ̀ ni kì í yí ọkàn rẹ̀ padà; nítorí kì í ṣe ènìyàn tí yóò yí ọkàn rẹ̀ padà.”

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí 1 Samuẹli 15:29

4

1 Samuẹli 15:11

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

“Èmi káàánú gidigidi pé mo fi Saulu jẹ ọba, nítorí pé ó ti yípadà kúrò lẹ́yìn mi, kò sì pa ọ̀rọ̀ mi mọ́.” Inú Samuẹli sì bàjẹ́ gidigidi, ó sì ké pe OLúWA ní gbogbo òru náà.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí 1 Samuẹli 15:11

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò