Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ 1 Kronika 22

1

1 Kronika 22:13

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

YCB

Nígbà náà ìwọ yóò sì ní àṣeyọrí tí ìwọ bá ṣe àkíyèsí láti mú àṣẹ àti ìdájọ́ àti òfin ti OLúWA ti fi fún Mose fun Israẹli ṣe. Bẹ́ẹ̀ ni ki ìwọ jẹ́ alágbára àti onígboyà. Má ṣè bẹ̀rù tàbí kí àyà má sì ṣe fò ọ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí 1 Kronika 22:13

2

1 Kronika 22:19

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

YCB

Nísinsin yìí, ẹ ṣí ọkàn yin páyà àti àyà yín sí àti wá OLúWA Ọlọ́run yín. Bẹ́ẹ̀ sì ni kọ́ ibi mímọ́ fún OLúWA Ọlọ́run. Bẹ́ẹ̀ ni kí ìwọ kí ó le gbé àpótí ẹ̀rí ti májẹ̀mú OLúWA àti ohun èlò mímọ́ tí ó jẹ́ ti Ọlọ́run, sínú ilé OLúWA tí a o kọ́ fún orúkọ OLúWA.”

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí 1 Kronika 22:19

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò