Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ O. Daf 7

1

O. Daf 7:17

Bibeli Mimọ

YBCV

Emi o yìn Oluwa gẹgẹ bi ododo rẹ̀: emi o si kọrin iyìn si orukọ Oluwa Ọga-ogo julọ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí O. Daf 7:17

2

O. Daf 7:10

Bibeli Mimọ

YBCV

Abo mi mbẹ lọdọ Ọlọrun ti o nṣe igbala olotitọ li aiya.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí O. Daf 7:10

3

O. Daf 7:11

Bibeli Mimọ

YBCV

Ọlọrun li onidajọ ododo, Ọlọrun si nbinu si enia buburu lojojumọ

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí O. Daf 7:11

4

O. Daf 7:9

Bibeli Mimọ

YBCV

Jẹ ki ìwa-buburu awọn enia buburu ki o de opin: ṣugbọn mu olotitọ duro: nitoriti Ọlọrun olododo li o ndan aiya ati inu wò.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí O. Daf 7:9

5

O. Daf 7:1

Bibeli Mimọ

YBCV

OLUWA, Ọlọrun mi, iwọ ni mo gbẹkẹ mi le: gbà mi lọwọ gbogbo awọn ti nṣe inunibini si mi, ki o si yọ mi kuro.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí O. Daf 7:1

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú O. Daf 7

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò