1
O. Daf 52:8
Bibeli Mimọ
YBCV
Ṣugbọn emi dabi igi olifi tutu ni ile Ọlọrun: emi gbẹkẹle ãnu Ọlọrun lai ati lailai.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 52:8
2
O. Daf 52:9
Emi o ma yìn ọ lailai nitoripe iwọ li o ṣe e: emi o si ma duro de orukọ rẹ; nitori ti o dara li oju awọn enia mimọ́ rẹ.
Ṣàwárí O. Daf 52:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò